Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 5:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n jẹ́ ọ̀kọrin: Ásáfù, Hémánì, Jédútúnì àti àwọn ọmọ wọn àti àwọn ẹbí wọn, wọ́n dúró ní igun ìlà oòrùn pẹpẹ náà wọ́n wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ túntún wọ́n ń lo ohun èlò orin kínnbálì, hápù àti líà. Ìwọ̀n ọgọ́fà àwọn àlùfaà tí wọ́n ń fun ìpè ni wọ́n tẹ̀lé wọn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 5

Wo 2 Kíróníkà 5:12 ni o tọ