Tó bẹ́ẹ̀ tí àwọn àlùfáà kò leè ṣiṣẹ́ ìsìn wọn nítorí ìkùku náà, nítorí ògo Olúwa kún inú tẹ́ḿpìlì Ọlọ́run.