Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 27:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni Bénáyà náà tí ó jẹ́ ọkùnrin ńlá láàrin àwọn ọgbọ̀n àti lórí àwọn ọgbọ̀n. Ọmọ Rẹ̀ Ámíṣábádì jẹ́ alákóso lórí ìpín tirẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:6 ni o tọ