Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 27:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olórí àwọn ọmọ ogun ẹlẹ́ẹ̀kẹta fún oṣù kẹta jẹ́ Bénáyà ọmọ Jéhóíádà àlùfáà. Ó jẹ́ olóyè, àwọn ọkùnrin ẹgbàá méjìlá ní ó wà ní ìpín tirẹ̀. (24,000).

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:5 ni o tọ