Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 27:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹlẹ́ẹ̀kẹrin fún oṣù kẹrin, jẹ́ Ásáhélì arákùnrin Jóábù: ọmọ Rẹ̀ Ṣébádáyà jẹ́ arọ́pò Rẹ̀. Ẹgbàá méjìlá ọkùnrin (24,000) ni ó wà ní ìpín Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:7 ni o tọ