Éfúráímù ti rẹ̀ dànùGbogbo rẹ̀ sì ti rọ,kò sì so èso,Bí wọ́n tilẹ̀ bímọ.Èmi ó pa àwọn ọmọ wọn tí wọ́n fẹ́ràn jùlọ.”