Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hósíà 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí gbogbo ìwà búburú tí wọ́n hù ní GílígálìMo kórìírà wọn níbẹ̀,Nítorí ìwà ẹ̀ṣẹ̀ wọn.Èmi yóò lé wọn jáde ní ilé miÈmi kò ní ní ìfẹ́ wọn mọ́ọlọ̀tẹ̀ ni gbogbo olórí wọn.

Ka pipe ipin Hósíà 9

Wo Hósíà 9:15 ni o tọ