Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 5:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn emi wi fun nyin, Ẹ fẹ awọn ọtá nyin, ẹ sure fun awọn ẹniti o nfi nyin ré, ẹ ṣõre fun awọn ti o korira nyin, ki ẹ si gbadura fun awọn ti nfi arankàn ba nyin lò, ti nwọn nṣe inunibini si nyin;

Ka pipe ipin Mat 5

Wo Mat 5:44 ni o tọ