Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Mat 5:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o le mã jẹ ọmọ Baba nyin ti mbẹ li ọrun: nitoriti o nmu õrùn rẹ̀ ràn sara enia buburu ati sara enia rere, o si nrọ̀jo fun awọn olõtọ ati fun awọn alaiṣõtọ.

Ka pipe ipin Mat 5

Wo Mat 5:45 ni o tọ