Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 5:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kiyesi i, ki ẹnikẹni ki o máṣe fi buburu san buburu fun ẹnikẹni; ṣugbọn ẹ mã lepa eyi ti iṣe rere nigbagbogbo, lãrin ara nyin, ati larin gbogbo enia.

Ka pipe ipin 1. Tes 5

Wo 1. Tes 5:15 ni o tọ