Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Tes 5:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awa mbẹ̀ nyin, ará, ki ẹ mã kìlọ fun awọn ti iṣe alaigbọran, ẹ mã tù awọn alailọkàn ninu, ẹ mã ràn awọn alailera lọwọ, ẹ mã mu sũru fun gbogbo enia.

Ka pipe ipin 1. Tes 5

Wo 1. Tes 5:14 ni o tọ