Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 11:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori nitõtọ kò yẹ ki ọkunrin ki o bò ori rẹ̀, niwọnbi on ti jẹ aworan ati ogo Ọlọrun: ṣugbọn obinrin ni iṣe ogo ọkunrin.

Ka pipe ipin 1. Kor 11

Wo 1. Kor 11:7 ni o tọ