Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kor 11:6 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori bi obinrin kò ba bo ori, ẹ jẹ ki o rẹ́ irun rẹ̀ pẹlu: ṣugbọn bi o bá ṣepe ohun itiju ni fun obinrin lati rẹ́ irun tabi lati fári rẹ̀, jẹ ki o bò ori.

Ka pipe ipin 1. Kor 11

Wo 1. Kor 11:6 ni o tọ