Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efe 6:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ẸNYIN ọmọ, ẹ mã gbọ ti awọn õbi nyin ninu Oluwa: nitoripe eyi li o tọ́.

2. Bọ̀wọ fun baba ati iya rẹ (eyi ti iṣe ofin ikini pẹlu ileri),

3. Ki o le dara fun ọ, ati ki iwọ ki o le wà pẹ li aiye.

Ka pipe ipin Efe 6