Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Efe 6:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ẹnyin baba, ẹ máṣe mu awọn ọmọ nyin binu: ṣugbọn ẹ mã tọ́ wọn ninu ẹkọ́ ati ikilọ Oluwa.

Ka pipe ipin Efe 6

Wo Efe 6:4 ni o tọ