Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Lefi si wẹ̀ ara wọn mọ́ kuro ninu ẹ̀ṣẹ, nwọn si fọ̀ aṣọ wọn; Aaroni si mú wọn wá li ọrẹ fifì siwaju OLUWA: Aaroni si ṣètutu fun wọn lati wẹ̀ wọn mọ́.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:21 ni o tọ