Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni Mose, ati Aaroni, ati gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, ṣe si awọn ọmọ Lefi: gẹgẹ bi gbogbo eyiti OLUWA paṣẹ fun Mose niti awọn ọmọ Lefi, bẹ̃li awọn ọmọ Israeli ṣe si wọn.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:20 ni o tọ