Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Num 8:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin eyinì ni awọn ọmọ Lefi si wọle lọ lati ṣe iṣẹ-ìsin ninu agọ́ ajọ niwaju Aaroni, ati niwaju awọn ọmọ rẹ̀: bi OLUWA ti paṣẹ fun Mose niti awọn ọmọ Lefi, bẹ̃ni nwọn ṣe si wọn.

Ka pipe ipin Num 8

Wo Num 8:22 ni o tọ