Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:44 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn sibẹ̀ ninu gbogbo eyina, nigbati nwọn ba wà ni ilẹ awọn ọtá wọn, emi ki yio tà wọn nù, bẹ̃li emi ki yio korira wọn, lati run wọn patapata, ati lati dà majẹmu mi pẹlu wọn: nitoripe Emi li OLUWA Ọlọrun wọn:

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:44 ni o tọ