Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:43 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si fi ilẹ na silẹ, on o si ní isimi rẹ̀, nigbati o ba di ahoro li aisí wọn; nwọn o si gbà ibawi ẹ̀ṣẹ wọn: nitoripe, ani nitoripe nwọn gàn idajọ mi, ati ọkàn wọn korira ìlana mi.

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:43 ni o tọ