Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Lef 26:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn nitori wọn emi o ranti majẹmu awọn baba nla wọn, ti mo mú lati ilẹ Egipti jade wá li oju awọn orilẹ-ède, ki emi ki o le ma ṣe Ọlọrun wọn: Emi li OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 26

Wo Lef 26:45 ni o tọ