Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:28 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina ni awa ṣe wipe, Yio si ṣe, nigbati nwọn ba wi bẹ̃ fun wa, tabi fun awọn iran wa lẹhinọla, awa o si wipe, Ẹ wò apẹrẹ pẹpẹ OLUWA, ti awọn baba wa mọ, ki iṣe fun ẹbọ sisun, bẹ̃ni ki iṣe fun ẹbọ; ṣugbọn o jasi ẹrí li agbedemeji awa ati ẹnyin.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:28 ni o tọ