Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki Ọlọrun má jẹ ki awa ki o ṣọ̀tẹ si OLUWA, ki awa si pada li oni kuro lẹhin OLUWA, lati mọ pẹpẹ fun ẹbọ sisun, fun ẹbọ ohunjije, tabi fun ẹbọ kan, lẹhin pẹpẹ OLUWA Ọlọrun wa ti mbẹ niwaju agọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:29 ni o tọ