Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 22:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ẹrí ni li agbedemeji awa ati ẹnyin, ati awọn iran wa lẹhin wa, ki awa ki o le ma fi ẹbọ sisun wa, ati ẹbọ wa, pẹlu ẹbọ alafia wa jọsìn fun OLUWA niwaju rẹ̀; ki awọn ọmọ nyin ki o má ba wi fun awọn ọmọ wa lẹhinọla pe, Ẹnyin kò ní ipín niti OLUWA.

Ka pipe ipin Joṣ 22

Wo Joṣ 22:27 ni o tọ