Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 17:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Manasse iyokù si ní ilẹ-iní gẹgẹ bi idile wọn; awọn ọmọ Abieseri, ati awọn ọmọ Heleki, ati awọn ọmọ Asrieli, ati awọn ọmọ Ṣekemu, ati awọn ọmọ Heferi, ati awọn ọmọ Ṣemida: awọn wọnyi ni awọn ọmọ Manasse ọmọ Josefu gẹgẹ bi idile wọn.

Ka pipe ipin Joṣ 17

Wo Joṣ 17:2 ni o tọ