Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 17:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

EYI si ni ipín ẹ̀ya Manasse; nitori on li akọ́bi Josefu. Bi o ṣe ti Makiri akọ́bi Manasse, baba Gileadi, nitori on ṣe ologun, nitorina li o ṣe ní Gileadi ati Baṣani.

Ka pipe ipin Joṣ 17

Wo Joṣ 17:1 ni o tọ