Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Joṣ 17:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn Selofehadi, ọmọ Heferi, ọmọ Gileadi, ọmọ Makiri, ọmọ Manasse, kò ní ọmọkunrin, bikoṣe ọmọbinrin: awọn wọnyi si li orukọ awọn ọmọbinrin rẹ̀, Mala, ati Noa, Hogla, Milka, ati Tirsa.

Ka pipe ipin Joṣ 17

Wo Joṣ 17:3 ni o tọ