Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2. Kro 24:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bẹ̃ni Joaṣi, ọba, kò ranti õre ti Jehoiada, baba rẹ̀, ti ṣe fun u, o si pa ọmọ rẹ̀. Nigbati o si nkú lọ, o wipe, Ki Oluwa ki o wò o, ki o si bère rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 24

Wo 2. Kro 24:22 ni o tọ