Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 28:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si pa ara dà, o si mu aṣọ miran wọ̀, o si lọ, awọn ọmọkunrin meji si pẹlu rẹ̀, nwọn si wá si ọdọ obinrin na li oru: on si wipe, emi bẹ̀ ọ, fi ẹmi abokusọ̀rọ da nkan fun mi, ki o si mu ẹniti emi o darukọ rẹ̀ fun ọ wá oke fun mi.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:8 ni o tọ