Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 28:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si wi fun awọn iranṣẹ rẹ̀ pe, Ẹ ba mi wá obinrin kan ti o ni ẹmi abokusọ̀rọ, emi o si tọ ọ lọ, emi o si bere lọdọ rẹ̀. Awọn iranṣẹ rẹ̀ si wi fun u pe, Wõ, obinrin kan ni Endori ti o ni ẹmi abokusọ̀rọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 28

Wo 1. Sam 28:7 ni o tọ