Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ si lọ iwá a. Nwọn si sọ fun Dafidi: o si sọkalẹ wá si ibi okuta kan, o si joko li aginju ti Maoni. Saulu si gbọ́, o si lepa Dafidi li aginju Maoni.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:25 ni o tọ