Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Saulu si nrin li apakan oke kan, Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ li apa keji oke na: Dafidi si yara lati sa kuro niwaju Saulu; nitoripe Saulu ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ ti rọ̀gba yi Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ ka lati mu wọn.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:26 ni o tọ