Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Sam 23:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si dide, nwọn si ṣaju Saulu lọ si Sifi: ṣugbọn Dafidi ati awọn ọmọkunrin rẹ̀ wà li aginju Maoni, ni pẹtẹlẹ niha gusu ti Jeṣimoni.

Ka pipe ipin 1. Sam 23

Wo 1. Sam 23:24 ni o tọ