Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 28:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati iwọ, Solomoni ọmọ mi, mọ̀ Ọlọrun baba rẹ, ki o si fi aiya pipé ati fifẹ ọkàn sìn i: nitori Oluwa a ma wá gbogbo aiya, o si mọ̀ gbogbo ete ironu: bi iwọ ba ṣafẹri rẹ̀, iwọ o ri i; ṣugbọn bi iwọ ba kọ̀ ọ silẹ on o ta ọ nù titi lai.

Ka pipe ipin 1. Kro 28

Wo 1. Kro 28:9 ni o tọ