Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 28:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi li oju gbogbo Israeli ijọ enia Oluwa, ati li eti Ọlọrun wa, ẹ ma pamọ́ ki ẹ si ma ṣafẹri gbogbo ofin Oluwa Ọlọrun nyin: ki ẹ le ni ilẹ rere yi, ki ẹ si le fi i silẹ li ogún fun awọn ọmọ nyin lẹhin nyin lailai.

Ka pipe ipin 1. Kro 28

Wo 1. Kro 28:8 ni o tọ