Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 19:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn ijoye awọn ọmọ Ammoni wi fun Hanuni pe, Iwọ rò pe Dafidi bu ọlá fun baba rẹ nitori ti o ran awọn olutunu si ọ? Kò ṣepe awọn iranṣẹ rẹ̀ wá si ọdọ rẹ lati rin wò, ati lati bi ṣubu ati lati ṣe ami ilẹ na?

Ka pipe ipin 1. Kro 19

Wo 1. Kro 19:3 ni o tọ