Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. Kro 19:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dafidi si wipe, Emi o ṣe ore fun Hanuni ọmọ Nahaṣi, nitoriti baba rẹ̀ ṣe ore fun mi. Dafidi si ran onṣẹ lati tù u ninu nitori baba rẹ̀. Bẹ̃ni awọn iranṣẹ Dafidi wá si ilẹ awọn ọmọ Ammoni, si ọdọ Hanuni lati tù u ninu.

Ka pipe ipin 1. Kro 19

Wo 1. Kro 19:2 ni o tọ