Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si mu ẹgbọrọ akọ-malu na ti a fi fun wọn, nwọn si ṣe e, nwọn si kepè orukọ Baali lati owurọ titi di ọ̀sangangan wipe, Baali! da wa lohùn. Ṣugbọn kò si ohùn, bẹ̃ni kò si idahùn. Nwọn si jó yi pẹpẹ na ka, eyiti nwọn tẹ́.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:26 ni o tọ