Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Elijah si wi fun awọn woli Baali pe, Ẹ yàn ẹgbọrọ akọ-malu kan fun ara nyin, ki ẹ si tètekọ ṣe e: nitori ẹnyin pọ̀: ki ẹ si kepè orukọ awọn ọlọrun nyin, ṣugbọn ẹ máṣe fi iná si i,

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:25 ni o tọ