Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, li ọ̀sangangan ni Elijah fi wọn ṣe ẹlẹya o si wipe, Ẹ kigbe lohùn rara, ọlọrun sa li on; bọya o nṣe àṣaro, tabi on nlepa, tabi o re àjo, bọya o sùn, o yẹ ki a ji i.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:27 ni o tọ