Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ si kepe orukọ awọn ọlọrun nyin, emi o si kepè orukọ Oluwa: Ọlọrun na ti o ba fi iná dahùn on na li Ọlọrun. Gbogbo awọn enia na si dahùn, nwọn si wipe, O wi i re.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:24 ni o tọ