Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio si ṣe bi emi o ti lọ kuro li ọdọ rẹ, Ẹmi Oluwa yio si gbe ọ lọ si ibi ti emi kò mọ̀; nigbati mo ba si de, ti mo si wi fun Ahabu, ti kò ba si ri ọ, on o pa mi: ṣugbọn emi, iranṣẹ rẹ, bẹ̀ru Oluwa lati igba ewe mi wá.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:12 ni o tọ