Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1. A. Ọba 18:13 Yorùbá Bibeli (YCE)

A kò ha sọ fun oluwa mi, ohun ti mo ṣe nigbati Jesebeli pa awọn woli Oluwa, bi mo ti pa ọgọrun enia mọ ninu awọn woli Oluwa li aradọta ninu ihò-okuta, ti mo si fi àkara pẹlu omi bọ́ wọn?

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 18

Wo 1. A. Ọba 18:13 ni o tọ