Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 9:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Njẹ nisisiyi fun igba diẹ, li a si fi ore-ọfẹ fun wa lati ọdọ Oluwa Ọlọrun wa wá lati salà, ati lati fi ẽkàn fun wa ni ibi mimọ́ rẹ̀, ki Ọlọrun wa ki o le mu oju wa mọlẹ, ki o si tun wa gbe dide diẹ ninu oko-ẹrú wa.

Ka pipe ipin Esr 9

Wo Esr 9:8 ni o tọ