Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esr 9:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati ọjọ awọn baba wa li awa ti wà ninu ẹbi nla titi di oni; ati nitori ẹ̀ṣẹ wa li a fi awa, awọn ọba wa, ati awọn alufa wa, le awọn ọba ilẹ wọnni lọwọ fun idà, fun igbèkun, ati fun ikogun, ati fun idamu oju, gẹgẹ bi o ti ri li oni oloni.

Ka pipe ipin Esr 9

Wo Esr 9:7 ni o tọ