Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 28:26 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn o si ma gbé inu rẹ̀ ni ibalẹ-aiya, nwọn o si kọ́ ile, nwọn o si gbìn ọgbà àjara; nitõtọ, nwọn o wà ni ibalẹ-aiya, nigbati emi bá ti mu idajọ mi ṣẹ si ara awọn ti ngàn wọn yi wọn kakiri, nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa Ọlọrun wọn.

Ka pipe ipin Esek 28

Wo Esek 28:26 ni o tọ