Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 28:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, Nigbati emi o bá ti kó ile Israeli jọ kuro lãrin awọn orilẹ-ède ti a tú wọn ká si, ti a o si yà mi si mimọ́ ninu wọn loju awọn keferi, nigbana ni nwọn o gbé ilẹ wọn ti mo ti fi fun Jakobu iranṣẹ mi.

Ka pipe ipin Esek 28

Wo Esek 28:25 ni o tọ