Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:37 Yorùbá Bibeli (YCE)

Si kiye si i, Emi o kó gbogbo awọn olufẹ rẹ jọ, awọn ẹniti iwọ ti ba jaiye, ati gbogbo awọn ti iwọ ti fẹ, pẹlu gbogbo awọn ti iwọ ti korira; ani emi o gbá wọn jọ kakiri si ọ, emi o si fi ihoho rẹ hàn wọn, ki nwọn ki o le ri gbogbo ihoho rẹ.

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:37 ni o tọ