Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Esek 16:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bayi ni Oluwa Ọlọrun wi; Nitoriti a dà ẹgbin rẹ jade, ti a si ri ihoho rẹ nipa panṣaga rẹ pẹlu awọn olufẹ rẹ, ati pẹlu gbogbo oriṣa irira rẹ, ati nipa ẹjẹ awọn ọmọ rẹ, ti iwọ fi fun wọn:

Ka pipe ipin Esek 16

Wo Esek 16:36 ni o tọ