Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Romu 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gba àmì ìkọlà bí ẹ̀rí iṣẹ́ rere nípa igbagbọ tí ó ní nígbà tí kò ì tíì kọlà. Nítorí èyí, ó di baba fún gbogbo àwọn tí ó ní igbagbọ láì kọlà, kí Ọlọrun lè kà wọ́n sí ẹni rere;

Ka pipe ipin Romu 4

Wo Romu 4:11 ni o tọ